Tí a bá ń parọ fún ara wa ni a má fi ọ̀rọ̀ sì abẹ ahọn sọ. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ sì ni wi pe nǹkan burú síi ní fún orile-ede Nàìjíríà. Àpẹẹrẹ wí pé ...
Read More
Home / Ọ̀rọ̀ Olóòtú
Showing posts with label Ọ̀rọ̀ Olóòtú. Show all posts
Showing posts with label Ọ̀rọ̀ Olóòtú. Show all posts
Sàràkí lè dá Buhari lágbo nu
Inúfu-àyàfu ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC wá báyìí pelu ahesọ ọ̀rọ̀ tí ń lọ kiri wí pé, Ààrẹ ilé igbimo asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí kò ní pẹ fi ẹg...
Read More
Ìkà tí ẹbi Abiola ṣe fún MKO ju ti IBB àti Abacha lọ
Ìròyìn tí kárí ayé wí pé wọn ti fi olóògbé Moshood Kashimawo Olawale Abiola jẹ òye idanilọla orile-ede Nàìjíríà tó gaju lọ, GCFR. Ṣùgbọ́n ẹ...
Read More
Ìgbà èwe: Mo pàdánù ọrẹ méjì tí mo fẹ́ràn ju
Ó ní ayajọ àwọn èwe lagbaye. Eléyìí sì. Mú mi rántí Musa, ọrẹ mi ìgbà èwe, ile iwe alakobẹrẹ láti pàdé. Mo fẹ́ràn Musa nítorí wí pé o jẹ ọ...
Read More
"Ẹ má gbàgbé ohun tí mo sọ": Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n JJ Okocha
JJ Okocha ẹni tí wọn fún ni Muhammet Yavuz gẹ́gẹ́ bí orúkọ tuntun ni ilu Turkey nígbà tí wọn fún un ní iwe àṣẹ láti jẹ ọmọ ìlú náà ni kókó ọ...
Read More
"Flora my flowa" Davido tí dá gobe silẹ
Mo fẹ́ràn láti máa kàwé. Orisirisi ìwé ni mo sì ti kà nípa òdòdó àti ìwúlò rẹ layika. Yàtọ̀ sí ẹ̀ṣọ́ ilé, fifi ojú kó òdòdó má n jẹ ki ènìy...
Read More
Funmilayo rin ihoho wọja, kò sinwin bẹẹ ni ò yà wèrè
Ẹni ja ìjàngbara kò yàtò ṣeni tí wọn forí rẹ fagbọn. Ẹni wọn forí rẹ fagbọn kìí dúró jẹ ẹ. Ayafi ẹni Olúwa bá ko yọ. Funmilayo RansomeKuti ...
Read More
Lẹta: "Ó ń semi bi kí n pa ara mi" - Obirin afẹsọna
Olayemi kíni mo lè ṣe? Ó ń ṣe mi bi kí n pa ara mi. Ọkùnrin tí èmi àti ẹ jọ ń fẹ́ ara wa bí ọdún kan sẹ́yìn, ní atí jọ ṣe ayẹyẹ introduction...
Read More
Ẹ polówó ọjà yín nibi: Irú ọjà wo lẹ́yìn ń tà?
Ni báyìí, àǹfààní tí wá fún yín láti ṣe ìkéde, ipolowo, ìpolongo lórí àwọn ìkànnì wá lórí ayélujára pẹlu irọrun. Ẹyin ẹ kàn kọ̀wé ranse sí ...
Read More
Ìdí tí àwọn ènìyàn fi pa Alfa Salami lórúkọ dà ní yìí
Oríṣiríṣi ogun, wàhálà àti ìdojúkọ ni ọmọ ẹ̀dá ń kọjú nílé ayé. Àwọn kan ségun, àwọn kan sì bogun lọ. Ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run nìkan ló lè gbé ẹ̀d...
Read More
Pàtàkì ayajọ olólùfẹ́ kìí se ibalopo abo-atakọ
Ayajo ololufe kìí se nípa ibalopo akọ-sabo, bíkòṣe láti fi ìfẹ́ hàn, imoriiri ìfẹ́ àti ajọyọ ìfẹ́ láàárín ènìyàn kan sì ìkejì, ebi àti ẹgbẹ́...
Read More
Ṣé ọjọ́ orí ṣe pàtàkì nínú ètò ìlú ṣíṣe?
Nínú èrò mi, mi ò ro wí pé ìṣòro Nàìjíríà yóò dópin nípa gbígba àwọn ọ̀dọ́ láàyè nínú isejọba nìkan. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ìdùnnú mi ni lati ...
Read More
Ẹ le kan sì Olayemi Oniroyin lórí nomba yìí +2348032394964 fún ikede àti ipolowo oja
Fún ipolowo àti ikede ẹ lè kan sì mi pelu nomba yii +2348032394964 yemoford@gmail.com Twitter/IG @OlayemiOniroyin www.olayemioniroyinblo...
Read More
Ẹ kaabọ sìnu oṣù tuntun ìdùnnú àti igbega
Ẹ kú ayọ̀ oṣù tuntun! Gbogbo ohun rere tuntun tí ọkàn onikaluku ń béèrè ní Ọlọ́run yóò ṣe. A kò ní rí ibanuje, ire lójú owó ń rí, ire la ma ...
Read More
Ìwúre fún àwọn agunbaniro tí wọ́n fe lọ sókè oya
Fún àwọn tí wọn gbaradi láti lọ fún agunbaniro ni akoko yii, mo gbàdúrà wí pé ààbò Eledumare tó dájú yóò wà lórí wọn. Àmìn #CorperSneh ...
Read More
Àwọn ènìyàn ta padà nígbà tá ń gòkè, le pada wúlò ta bá ń sòkalẹ̀ bọ̀
Má gbegbe awon olóore rẹ nígbà tó kéré. Ma seranti awon eniyan ti won dúró tì ọ nígbà tí kò sì ohunkóhun lọ́wọ́ rẹ nígbà to ba gòkè. Awon Y...
Read More
Ni Ìpínlẹ̀ Anambra, awon omo ileewe tí wọ́n ṣe dáadáa ní kíláàsì gba ẹ̀bùn ewúré
Ni Ìpínlẹ̀ Anambra, awon omo ileewe tí wọ́n ṣe dáadáa ní kíláàsì gba ẹ̀bùn ewúré Kérésìmesì tí dùn
Read More
Ìdí pàtàkì tí ẹ̀bùn ọdún fi ṣe pàtàkì
Ìkéde pàtàkì fún àwọn ènìyàn pàtàkì tí wọ́n rí ÌDÍ pàtàkì tí ìkéde yìí fi jẹ́ pàtàkì. Àwọn ènìyàn pàtàkì tí rí ìdí pàtàkì láti fún ara wọn...
Read More
Má rọra, iro láyé; òtítọ́ kò sí níbikíbi
Lọ́jọ́ tí Buhari ṣe ọjọ́ ìbí, àìmọye gomina ni won peju sile àgbàrá Abuja. Won ki Buhari tẹrin-tẹyẹ. Awon kan tilẹ ń kí ni oriki ìdílé tí B...
Read More
Tí ọmọdé bá ṣubú...
MoẸyin ènìyàn mi, máa bẹ yín láti fi òye gidi gbé àlàyé mi. Nítorí yóò tako ohun tẹ̀ẹ́ mọ tàbí ìgbàgbọ́ yin. Ti ọmọ iya méjì bá wo yèwù, t...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)